Idahun ibeere Kayode @Ogundamisi: 'Ologbon di ori eja mu" ati "Gidigba osi ilekun" Olayemi Oniroyin 9/13/2017 01:36:00 pm Add Comment Edit Eku Owuro omo Karo o ji ire; ejo ki ni itumo owe Yoruba 'Ologbon di ori eja mu" ati "Gidigba osi ilekun"? — Kayode O... Read More
Naijiria ti pada si ese aaro, won ti n kosu lo ta loke okun Olayemi Oniroyin 6/30/2017 09:29:00 pm Add Comment Edit Ile Naijiria ti bere si ni ko nnkan ogbin lo ta loke okun bayii pelu bi won se bere pelu isu tita si oke okun. Awon onwoye eto oro aje... Read More
Ẹja ti n won pe ni Shellfish se awon eniyan ni kayefi lode agbaye Olayemi Oniroyin 11/26/2016 12:51:00 pm Add Comment Edit E ma jẹ ki n parọ fun yin, aimoye ohun abẹmi lo wa nisalẹ omi eleyii ti Olorun da fun igbadun omo eniyan. Orisii ẹja kan ni yii eleyi... Read More
"Tomati to wọn bi oju, Boko Haram lo fa sababi" Lai Muhammed Olayemi Oniroyin 6/02/2016 05:41:00 pm Add Comment Edit Minisita fun etigbọ ati asa nile yii, Alaaji Lai Muhammed, ti wi pe, owongogo tomati loja ko se lẹyin wahala awọn Boko Haram eleyii to m... Read More
Ohun ti tomato n so loja ni yii Olayemi Oniroyin 5/24/2016 06:52:00 pm Add Comment Edit Awon eniyan ti bere si so nipa ohun ti tomato n soloja bayii nipa iye owo ti won ra elo obe naa. Awon kan tile so wi pe tomato paste lawo... Read More